Siirry suoraan sisältöön
?ló?run, Níbo Lo Wá?
?ló?run, Níbo Lo Wá?
Tallenna

?ló?run, Níbo Lo Wá?

Lue Adobe DRM-yhteensopivassa e-kirjojen lukuohjelmassaTämä e-kirja on kopiosuojattu Adobe DRM:llä, mikä vaikuttaa siihen, millä alustalla voit lukea kirjaa. Lue lisää

A bí Adé?lá ?r?olúwa Adéf?`s?` ní ìpínl?` Ògùn ní oríl?` èdè Nàìjíríà. Ó ?e èwe r?` nínú ay?` àti ìdùnnú. Àw?n òbí r?` àgbà ní ìdílé ìyá ló t?´ ? dàgbà p?`lú ìf?´ tó wàyàmì àti ?`k?´ ìwé tó yè kooro, òun náà sì dara p?` m?´ ?gb?´ ak?rin agbègbè ib?`. ?ùgbó?n n?kan yí bìrí nígbà tí ó kó sí wàhálà ab?´ ilé látàrí ìjìyà tí ó n rí láti ?`d?` ?k? r?`. Inú làásìgbò ìjìyà ara àti ?kàn yìí ló wà tí ó fi pàdánù àw?n ìbejì ?kùnrin r?` méjèèjì tí ó bí ní kògbókògbó.

Nínú ?dún 2019, ?m?kùnrin r?`, àbísìkejì, tí ó fìgbà kan j?´ ?m? ogun ojú omi il?` Am?´ríkà náà tún pa ara r?`. L?´yìn èyí ni Adé?lá tún rí àw?n ?`r?` kòbákùngbé tí ?k? r?` k? nípa r?` sí orí ?`r? ayélujára kà dé ibi pé òun lòun fa ikú ?m? àw?n ?`hún.

Ìrora, ìf?´, àti ìgbàgb?´ Adé?lá fara hàn kedere nínú ìtàn àgb?´gbárímú yìí tí ó gbé kal?` ní ìrètí pé yóò dé etígb?`?´ àw?n tí yóò wúlò fún.

"Nínú ìwé yìí, Adé?lá gbé ìtàn akíkanjú obìnrin kan tí ó dojú k? wàhálà ab?´le kal?`. L?´yìn-ò-r?yìn, p?`lú ìrànl?´w?´ ?ló?run, ó jáwé olúborí." Iloh, Friday Okechukwu (Ph. D)

ISBN
9781636031217
Kieli
Yoruba
Julkaisupäivä
22.11.2021
Formaatti
  • Epub - Adobe DRM
Lue e-kirjoja täällä
  • Lue e-kirja mobiililaitteella/tabletilla
  • Lukulaite
  • Tietokone